Igi ti da, Erin wo, Ajanaku ti sun bii oke, ọfọ nla si tun ti sẹ ni agbo awọn osere tiata Yoruba, eyi to mu ọmọ ẹgbẹ gbajumọ osere tiata miran lọ. Orukọ oloogbe gbajumọ osere tiata naa ni Aarẹ Yemi ...
Ilumọọka oṣere sinima ni Naijiria, Funkẹ Akindele ti ọpọ eeyan mọ si ‘Jẹnifa’ ti ṣalaye pe kii ṣe itan iya oun loun fi kọ sinima ‘A Tirbe called Judah’ to n mi igboro lọwọ kaakiri agbaye bayii. Funkẹ ...